#Music: Adeyemi Oluwadamilare - Kààbo | @ewordradio




Here is a nice Christmas tune from the stables of Adeyemi oluwadamilare titled KAABO (WELCOME) a song that welcomes the saviour of the world to the earth. Download and listen to it.











Lyrics Of Kààbo


(Chorus)


Lead: Kaabo o kaabo o s'aye o


All: Emmanueli kaabo o s'aye o/2X


Lead: Olutunu wa kaabo o s'aye o


All: Emmanueli kaabo o s'aye o


Lead: Oludande wa kaabo o s'aye o


All: Emmanueli kaabo o s'aye o








Solo1:


Oba t'abi fun wa nitori t'emi ati re o wa s'aye o lati gbawa la


ninu ese wa olutunnu wa ni olusegun funwa alaabo wa ni


Emmanueli kaabo o s'aye o








Solo2:


Unto us a child is born a child is given,He shall be called


wonderful counsellor,mighty God everlasting Father the king of


kings Emmanueli kaabo o s'aye o








Bridge:


Araye eyo,araye ejo eyo,ati bi abi olugbala funwa/3X


Interlude by talking drum








Call: Alade alafia kaabo o s'aye o


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o


Call: Olumoran okan wa kaabo o s'aye o


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o


Call: Oba to n fi mimo bora bi aso o kaabo o


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o


Call: Olufe okan mi kaabo o s'aye ooooo


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o


Call: Olowogbogboro ti n yo'mo re loofin aye kaabo o


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o


Call: The lover of our soul kaabo o s'aye oooo


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o


Call: Erujeje ni o kaabo o s'aye ooo


(All): Emmanueli kaabo o s'aye o

Post a Comment

Previous Post Next Post